Please FOLLOW & LIKE our PAGE on:

GOSPEL SONGS LYRICS NIGERIAN SONGS VIDEOS

Download Kay Wonder – Olorun Ti A ko Ri (Mp3, Lyrics, Video)

 
Kay Wonder – Olorun Ti A ko Ri (Mp3, Lyrics, Video)

Kay Wonder – Olorun Ti A ko Ri (Mp3, Lyrics, Video)

Prolific, Nigerian Gospel Song Musician Kay Wonder Presents To Us New Song Titled “Olorun Ti A ko Ri” Mp3 Download.

This Track “Olorun Ti A ko Ri” is an Amazing Project that will surely worth a place in your heart if you are a lover of sure Gospel music.

Download Olorun Ti A ko Ri Mp3 By Kay Wonder

DOWNLOAD MP3

Olorun Ti A ko Ri video By Kay Wonder

Olorun Ti A ko Ri lyrics By Kay Wonder

Olorun tawa o ri
ta n rise re
Olorun tawa o ri
ta n rise re
Ari lara Okun ato sa
Ari lara Ofurufu Olorun tawa ori
ta nri ise re

Olorun tawa o ri
ta n rise re
Olorun tawa o ri
ta n rise re
Ari lara Okun ato sa
Ari lara Ofurufu Olorun tawa ori

Oforun Joba Osan, Ofosupa joba oru
Oforun Joba Osan, Ofosupa joba oru
Pelu kiki Oro re Kiki agbara
On gbe ile aye sori agbami
Eni ti iri re dabi iro iji
Akoyin sire bi mona mona
Ani aye raye
Latowo re ni

Also  Download Bizzle – Little Light (Mp3, lyrics, Video)

Olorun tawa o ri
ta n rise re
Olorun tawa o ri
ta n rise re
Ari lara Okun ato sa
Ari lara Ofurufu Olorun tawa ori
ta nri ise re

Oba to je o
taye torun mi titi
Kile ole se
tale oju lo
Oba to je o
taye torun mi titi
Kile ole se
ato fara ti

Ki le o le se
tale oju lo
Ki le o le se
tale oju lo
Oba to je taye torun
Mi ti
Ki l o le se Ato farati

Ari lara Okun ato sa
Ari lara Ofurufu Olorun tawa ori
ta nri ise re
Ari lara Okun ato sa
Ari lara Ofurufu Olorun tawa ori
ta nri ise re

Ari lara Okun ato sa
Ari lara Ofurufu Olorun tawa ori
ta nri ise re
Ari lara Okun ato sa
Ari lara Ofurufu Olorun tawa ori
ta nri ise re

Leave a Comment