Home GOSPEL SONGS Download Bunmi Akinnanu – Dabira (Mp3, lyrics, Video)

Download Bunmi Akinnanu – Dabira (Mp3, lyrics, Video)

0
Bunmi Akinnanu – Dabira (Mp3, lyrics, Video)
Bunmi Akinnanu – Dabira (Mp3, lyrics, Video)

Quick Rising, Nigerian Christian Gospel Song Musician Bunmi Akinnanu Presents To Us New Song Titled “ Dabira ” Mp3 Download, “ Dabira ” Song comes with the Mp3 Audio With An Interesting Lyrics And The official Video.

This Track “ Dabira” is an Amazing Project that will surely worth a place in your heart if you are a lover of sure Gospel music.

Download Dabira Mp3 By Bunmi Akinnanu

DOWNLOAD MP3

Dabira video By Bunmi Akinnanu

Dabira lyrics By Bunmi Akinnanu

baba modupe f’ore ti o se laye mi baba modupe f’ore ti o se funmi o pa mi l’erin ayo o s’egan aye mi d’ogo baba modupe f’ore ti o se funmi baba modupe f’ore ti o se laye mi baba modupe f’ore ti o se funmi o pa mi l’erin ayo

Lodun ti mo wa yi yio dara

o s’egan aye mi d’ogo

baba modupe f’ore ti o se funmi mo mope wa/3x mo mope wa/3x aaa ah mo mope wa/3x fun jesu mo mope wa/3x aaa ah mo mope wa/3x fun jesu mo mope wa/3x aaa ah

mo k’hallelujah/3x si jesu mo mope wa/3x aaa ah ope mi naa ree tewo gbope mi fun aanu ti mo ri gbayen baba gbope mi awa n yin baba awa n yin baba f’ore tose ninu aye wa awa n yin baba aah mi o d’ogba ewon, o pa mi mo emi nyin baba emi eni eyin ojosi reo emi nyin baba lato ri atan toti wami ri emi nyin baba ogbe mi joko pel’omo alade emi nyin baba oro mi tope otun j’ope lo emi nyin baba oro wa tope otun j’ope lo awa nyin baba amope wa amuyin wa ooo gbopeee gbope sir amope wa amuyin wa ooo gbopeee gbope sir kabiosi mole mio peri oba mo duro mo k’oba mo bere mo k’oba mo dobalee mo k’oba mo yi gbirigbiri niwaju oba oba to n fobaje, oba to tun r’oba loye ijoye lepo jaburata, okan sha loba gbogbo won ashoro kolu bii ogiri gbigbe oba to gagaga t’eni kan o ri oba toloyun ara re totun sorare loruko baba mi iba arogundade o, yee arogunmashojo o kiki ola kiki ogo kiki agbara muni muni tuni tuni pin ni pin ni you’re omniscient omnipotent omni everything emi ni masheberu aa amope wa amuyin wa o gbopee gbope sir moti gbadura si baba moti gbadura si omo moti b’emimimo soro p’oni lati dara funmi moti gbadura mosi to boluwa so lodun ti mo wa yii yio dara funmi ati gbadura asi ti boluwa so lodun ti awa yii yio dara fun wa lodun ti awa yii yi oni lati dara funwa lodun ti mo wa yi yio dara funmi lodun ti mo wayi oni lati dara fun mi lodun ti mo wa yi yio dara lodun ti mo wayi moni lati laluyo o lodun ti mo wa yi yio dara lodun ti mo wayi o moni lati kolemole lodun ti mo wa yi yio dara gbogbo amubo ayemi mo dagbere funwon lodun ti mo wayii yio dara fun mi ekun asuundake oya gberu reo lodun ti mo wa yi yio dara emi ko loni o lodun ti mo wa yi yio dara emi komo nibanuje otami lonii lodun ti mo wa yi yio dara emi ko olodun ti mo wa yi yio dara dabira olorun unnn maje kogo mi o womi baba jekin gbenu ogo shola o baba ogo mi mashe je ko womi elesumare baba mo gbo ju le o ogo mi mashe je ko womi eledumare bami she dabira olorun unnn maje kogo mi o womi baba jekin gbenu ogo shola o baba gb’ohun mo dawole koma yori si rere jekin gbenu ogo shola o baba emi ni emi ko koromi dariyanjiyan lodun yii jekin gbenu ogo shola o baba

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here